1
ORIN DAFIDI 90:12
Yoruba Bible
Nítorí náà kọ́ wa láti máa ka iye ọjọ́ orí wa, kí á lè kọ́gbọ́n.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:12
2
ORIN DAFIDI 90:17
Jẹ́ kí ojurere OLUWA Ọlọrun wa wà lára wa, fi ìdí iṣẹ́ ọwọ́ wa múlẹ̀, jẹ́ kí iṣẹ́ ọwọ́ wa fi ìdí múlẹ̀.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:17
3
ORIN DAFIDI 90:14
Fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tẹ́ wa lọ́rùn ní òwúrọ̀, kí á lè máa yọ̀, kí inú wa sì máa dùn ní gbogbo ọjọ́ ayé wa.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:14
4
ORIN DAFIDI 90:2
Kí o tó dá àwọn òkè, ati kí o tó dá ilẹ̀ ati ayé, láti ayérayé, ìwọ ni Ọlọrun.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:2
5
ORIN DAFIDI 90:1
OLUWA, ìwọ ni o ti jẹ́ ibi ààbò wa láti ìrandíran.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:1
6
ORIN DAFIDI 90:4
Nítorí pé lójú rẹ, ẹgbẹrun ọdún dàbí àná, tabi bí ìṣọ́ kan ní òru.
Ṣàwárí ORIN DAFIDI 90:4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò