1
ÌFIHÀN 15:4
Yoruba Bible
Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ, Oluwa? Ta ni kò ní fi ògo fún orúkọ rẹ? Nítorí ìwọ nìkan ni ó pé, nítorí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè yóo wá, wọn yóo júbà níwájú rẹ, nítorí òdodo rẹ farahàn gbangba.”
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ÌFIHÀN 15:4
2
ÌFIHÀN 15:1
Mo tún rí ohun abàmì mìíràn ní ọ̀run, ohun ńlá ati ohun ìyanu: àwọn angẹli meje tí àjàkálẹ̀ àrùn meje ti ìkẹyìn wà ní ìkáwọ́ wọn, nítorí pé àwọn ni wọ́n mú ibinu Ọlọrun wá sí òpin.
Ṣàwárí ÌFIHÀN 15:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò