1
ORIN SOLOMONI 3:1
Yoruba Bible
Mo wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́, lórí ibùsùn mi lálẹ́, mo wá a, ṣugbọn n kò rí i; mo pè é, ṣugbọn kò dáhùn.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 3:1
2
ORIN SOLOMONI 3:2
N óo dìde nisinsinyii, n óo sì lọ káàkiri ìlú, n óo wá ẹni tí ọkàn mi fẹ́, ní gbogbo òpópónà ati ní gbogbo gbàgede. Mo wá a ṣugbọn n kò rí i.
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 3:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò