1
ORIN SOLOMONI 4:7
Yoruba Bible
O dára gan-an ni, olùfẹ́ mi! O dára dára, o ò kù síbìkan, kò sí àbààwọ́n kankan lára rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 4:7
2
ORIN SOLOMONI 4:9
O ti kó sí mi lẹ́mìí, arabinrin mi, iyawo mi, ẹ̀ẹ̀kan náà tí o ti ṣíjú wò mí, pẹlu nǹkan ọ̀ṣọ́ tí ó wà lọ́rùn rẹ, ni o ti kó sí mi lórí.
Ṣàwárí ORIN SOLOMONI 4:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò