ORIN SOLOMONI 4:7

ORIN SOLOMONI 4:7 YCE

O dára gan-an ni, olùfẹ́ mi! O dára dára, o ò kù síbìkan, kò sí àbààwọ́n kankan lára rẹ.