1
I. Sam 15:22
Bibeli Mimọ
Samueli si wipe, Oluwa ha ni inu-didun si ọrẹ sisun ati ẹbọ bi pe ki a gbà ohùn Oluwa gbọ́? kiye si i, igbọran sàn jù ẹbọ lọ, ifetisilẹ̀ si sàn jù ọra àgbo lọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Sam 15:22
2
I. Sam 15:23
Nitoripe iṣọtẹ dabi ẹ̀ṣẹ afọṣẹ, ati agidi gẹgẹ bi ìwa buburu ati ibọriṣa. Nitoripe iwọ kọ̀ ọ̀rọ Oluwa, on si kọ̀ ọ li ọba.
Ṣàwárí I. Sam 15:23
3
I. Sam 15:29
Agbara Israeli kì yio ṣeke bẹ̃ni kì yio si ronupiwada: nitoripe ki iṣe ẹda ti yio fi ronupiwada.
Ṣàwárí I. Sam 15:29
4
I. Sam 15:11
Emi kãnu gidigidi ti emi fi Saulu jọba: nitoriti o ti yipada lẹhin mi, kò si mu ọ̀rọ mi ṣẹ. O si ba Samueli ninu jẹ gidigidi; on si kepe Oluwa ni gbogbo oru na.
Ṣàwárí I. Sam 15:11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò