1
I. Tes 1:2-3
Bibeli Mimọ
Awa ndupẹ lọwọ Ọlọrun nigbagbogbo fun gbogbo nyin, awa nṣe iranti nyin ninu adura wa; Li aisimi li awa nranti iṣẹ igbagbọ́ nyin ati lãla ifẹ ati sũru ireti nyin ninu Oluwa wa Jesu Kristi, niwaju Ọlọrun ati Baba wa
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí I. Tes 1:2-3
2
I. Tes 1:6
Ẹnyin si di alafarawe wa, ati ti Oluwa, lẹhin ti ẹnyin ti gbà ọ̀rọ na ninu ipọnju ọ̀pọlọpọ, pẹlu ayọ̀ Ẹmí Mimọ́
Ṣàwárí I. Tes 1:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò