1
II. Kro 18:13
Bibeli Mimọ
Mikaiah si wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, ani, eyiti Ọlọrun mi ba wi li emi o sọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí II. Kro 18:13
2
II. Kro 18:22
Njẹ nisisiyi, kiyesi i, Oluwa ti fi ẹmi eke si ẹnu gbogbo awọn woli rẹ wọnyi, Oluwa si ti sọ ibi si ọ.
Ṣàwárí II. Kro 18:22
3
II. Kro 18:20
Nigbana ni ẹmi na jade wá, o si duro niwaju Oluwa, o si wipe, Emi o tàn a. Oluwa si wi fun u pe, Bawo?
Ṣàwárí II. Kro 18:20
4
II. Kro 18:19
Oluwa si wipe, Tani yio tàn Ahabu, ọba Israeli, ki o le gòke lọ ki o si le ṣubu ni Ramoti-Gileadi? Ekini si sọ bayi, ekeji si sọ miran.
Ṣàwárí II. Kro 18:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò