II. Kro 18:13

II. Kro 18:13 YBCV

Mikaiah si wipe, Bi Oluwa ti mbẹ, ani, eyiti Ọlọrun mi ba wi li emi o sọ.