1
Heb 10:25
Bibeli Mimọ
Ki a má mã kọ ipejọpọ̀ ara wa silẹ, gẹgẹ bi àṣa awọn ẹlomiran; ṣugbọn ki a mã gbà ara ẹni niyanju: pẹlupẹlu bi ẹnyin ti ri pe ọjọ nì nsunmọ etile.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Heb 10:25
2
Heb 10:24
Ẹ jẹ ki a yẹ ara wa wo lati rú ara wa si ifẹ ati si iṣẹ rere
Ṣàwárí Heb 10:24
3
Heb 10:23
Ẹ jẹ ki a dì ijẹwọ ireti wa mu ṣinṣin li aiṣiyemeji; (nitoripe olõtọ li ẹniti o ṣe ileri;)
Ṣàwárí Heb 10:23
4
Heb 10:36
Nitori ẹnyin kò le ṣe alaini sũru, nitori igbati ẹnyin ba ti ṣe ifẹ Ọlọrun tan, ki ẹnyin ki o le gbà ileri na.
Ṣàwárí Heb 10:36
5
Heb 10:22
Ẹ jẹ ki a fi otitọ ọkàn sunmọ tosi ni ẹ̀kún igbagbọ́, ki a si wẹ̀ ọkàn wa mọ́ kuro ninu ẹri-ọkàn buburu, ki a si fi omi mimọ́ wẹ̀ ara wa nù.
Ṣàwárí Heb 10:22
6
Heb 10:35
Nitorina ẹ máṣe gbe igboiya nyin sọnu, eyiti o ni ère nla.
Ṣàwárí Heb 10:35
7
Heb 10:26-27
Nitori bi awa ba mọ̃mọ̀ dẹṣẹ lẹhin igbati awa ba ti gbà ìmọ otitọ kò tun si ẹbọ fun ẹ̀ṣẹ mọ́, Bikoṣe ireti idajọ ti o ba ni lẹrù, ati ti ibinu ti o muná, ti yio pa awọn ọtá run.
Ṣàwárí Heb 10:26-27
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò