1
Isa 48:17-18
Bibeli Mimọ
Bayi li Oluwa wi, Olurapada rẹ, Ẹni-Mimọ Israeli: Emi li Oluwa Ọlọrun rẹ, ti o kọ́ ọ fun èrè, ẹniti o tọ́ ọ li ọ̀na ti iwọ iba ma lọ. Ibaṣepe iwọ fi eti si ofin mi! nigbana ni alafia rẹ iba dabi odo, ati ododo rẹ bi ìgbi-omi okun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Isa 48:17-18
2
Isa 48:10
Wò o, emi ti dà ọ, ṣugbọn ki iṣe bi fadaka; emi ti yan ọ ninu iná ileru wahala.
Ṣàwárí Isa 48:10
3
Isa 48:11
Nitori emi tikalami, ani nitori ti emi tikala mi, li emi o ṣe e, nitori a o ha ṣe bà orukọ mi jẹ? emi kì yio si fi ogo mi fun ẹlomiran.
Ṣàwárí Isa 48:11
4
Isa 48:22
Alafia kò si fun awọn enia buburu, li Oluwa wi.
Ṣàwárí Isa 48:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò