1
Jer 10:23
Bibeli Mimọ
Oluwa! emi mọ̀ pe, ọ̀na enia kò si ni ipa ara rẹ̀: kò si ni ipá enia ti nrin, lati tọ́ iṣisẹ rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Jer 10:23
2
Jer 10:6
Kò si ẹnikan ti o dabi Iwọ Oluwa! iwọ tobi, orukọ rẹ si tobi ni agbara!
Ṣàwárí Jer 10:6
3
Jer 10:10
Ṣugbọn Oluwa, Ọlọrun otitọ ni, on ni Ọlọrun alãye, ati Ọba aiyeraiye! aiye yio warìri nigbati o ba binu, orilẹ-ède kì yio le duro ni ibinu rẹ̀.
Ṣàwárí Jer 10:10
4
Jer 10:24
Oluwa kilọ fun mi, ṣugbon ni idajọ ni, ki o máṣe ni ibinu rẹ, ki iwọ ki o má sọ mi di asan.
Ṣàwárí Jer 10:24
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò