1
Owe 12:25
Bibeli Mimọ
Ibinujẹ li aiya enia ni idori rẹ̀ kọ odò; ṣugbọn ọ̀rọ rere ni imu u yọ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 12:25
2
Owe 12:1
ẸNIKẸNI ti o fẹ ẹkọ́, o fẹ ìmọ: ṣugbọn ẹniti o korira ibawi, ẹranko ni.
Ṣàwárí Owe 12:1
3
Owe 12:18
Awọn kan mbẹ ti nyara sọ̀rọ lasan bi igunni idà; ṣugbọn ahọn ọlọgbọ́n, ilera ni.
Ṣàwárí Owe 12:18
4
Owe 12:15
Ọ̀na aṣiwere tọ li oju ara rẹ̀: ṣugbọn ẹniti o fetisi ìgbimọ li ọlọgbọ́n.
Ṣàwárí Owe 12:15
5
Owe 12:16
Ibinu aṣiwere kò pẹ imọ̀: ṣugbọn amoye enia bò itiju mọlẹ.
Ṣàwárí Owe 12:16
6
Owe 12:4
Obinrin oniwa-rere li ade ọkọ rẹ̀: ṣugbọn eyi ti ndojuti ni dabi ọyún ninu egungun rẹ̀.
Ṣàwárí Owe 12:4
7
Owe 12:22
Irira loju Oluwa li ahọn eke; ṣugbọn awọn ti nṣe rere ni didùn-inu rẹ̀.
Ṣàwárí Owe 12:22
8
Owe 12:26
Olododo tọ́ aladugbo rẹ̀ si ọ̀na; ṣugbọn ọ̀na awọn enia buburu tàn wọn jẹ.
Ṣàwárí Owe 12:26
9
Owe 12:19
Ete otitọ li a o mu duro lailai; ṣugbọn ahọn eke, ìgba diẹ ni.
Ṣàwárí Owe 12:19
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò