1
Owe 14:12
Bibeli Mimọ
Ọ̀na kan wà ti o dabi ẹnipe o dara li oju enia, ṣugbọn opin rẹ̀ li ọ̀na ikú.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 14:12
2
Owe 14:30
Ọkàn ti o yè kõro ni ìye ara; ṣugbọn ilara ni ibajẹ egungun.
Ṣàwárí Owe 14:30
3
Owe 14:29
Ẹniti o ba lọra ati binu, o ni ìmọ pupọ; ṣugbọn ẹniti o ba yara binu o gbe wère leke.
Ṣàwárí Owe 14:29
4
Owe 14:1
ỌLUKULUKU ọlọgbọ́n obinrin ni kọ́ ile rẹ̀: ṣugbọn aṣiwere a fi ọwọ ara rẹ̀ fà a lulẹ.
Ṣàwárí Owe 14:1
5
Owe 14:26
Ni ibẹ̀ru Oluwa ni igbẹkẹle ti o lagbara: yio si jẹ ibi àbo fun awọn ọmọ rẹ̀.
Ṣàwárí Owe 14:26
6
Owe 14:27
Ibẹ̀ru Oluwa li orisun ìye, lati kuro ninu ikẹkùn ikú.
Ṣàwárí Owe 14:27
7
Owe 14:16
Ọlọgbọ́n enia bẹ̀ru, o si kuro ninu ibi; ṣugbọn aṣiwère gberaga, o si da ara rẹ̀ loju.
Ṣàwárí Owe 14:16
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò