1
Owe 16:3
Bibeli Mimọ
Kó iṣẹ rẹ le Oluwa lọwọ, a o si fi idi ìro-inu rẹ kalẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 16:3
2
Owe 16:9
Aiya enia ni ngbìmọ ọ̀na rẹ̀, ṣugbọn Oluwa li o ntọ́ itẹlẹ rẹ̀.
Ṣàwárí Owe 16:9
3
Owe 16:24
Ọrọ didùn dabi afara oyin, o dùn mọ ọkàn, o si ṣe ilera fun egungun.
Ṣàwárí Owe 16:24
4
Owe 16:1
IMURA aiya, ti enia ni, ṣugbọn lati ọdọ Oluwa ni idadùn ahọn.
Ṣàwárí Owe 16:1
5
Owe 16:32
Ẹniti o lọra ati binu, o san jù alagbara lọ; ẹniti o si ṣe akoso ẹmi rẹ̀, o jù ẹniti o ṣẹgun ilu lọ.
Ṣàwárí Owe 16:32
6
Owe 16:18
Igberaga ni iṣaju iparun, agidi ọkàn ni iṣaju iṣubu.
Ṣàwárí Owe 16:18
7
Owe 16:2
Gbogbo ọ̀na enia li o mọ́ li oju ara rẹ̀; ṣugbọn Oluwa li o ndiwọ̀n ọkàn.
Ṣàwárí Owe 16:2
8
Owe 16:20
Ẹniti o fi oye ṣe ọ̀ran yio ri ire; ẹniti o si gbẹkẹ le Oluwa, ibukún ni fun u.
Ṣàwárí Owe 16:20
9
Owe 16:8
Diẹ pẹlu ododo, o san jù ọrọ̀ nla lọ laisi ẹtọ́.
Ṣàwárí Owe 16:8
10
Owe 16:25
Ọ̀na kan wà ti o dabi ẹnipe o dara fun enia, ṣugbọn opin rẹ̀ li ọ̀na ikú.
Ṣàwárí Owe 16:25
11
Owe 16:28
Alayidayida enia dá ìja silẹ: asọ̀rọkẹlẹ yà awọn ọrẹ́ ni ipa.
Ṣàwárí Owe 16:28
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò