1
Owe 17:17
Bibeli Mimọ
Ọrẹ́ a ma fẹni nigbagbogbo, ṣugbọn arakunrin li a bi fun ìgba ipọnju.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 17:17
2
Owe 17:22
Inu-didùn mu imularada rere wá: ṣugbọn ibinujẹ ọkàn mu egungun gbẹ.
Ṣàwárí Owe 17:22
3
Owe 17:9
Ẹniti o bò ẹ̀ṣẹ mọlẹ, o nwá ifẹ; ṣugbọn ẹniti o tun ọ̀ran hú silẹ, o yà ọrẹ́ nipa.
Ṣàwárí Owe 17:9
4
Owe 17:27
Ẹniti o ni ìmọ, a ṣẹ́ ọ̀rọ rẹ̀ kù: ọlọkàn tutu si li amoye enia.
Ṣàwárí Owe 17:27
5
Owe 17:28
Lõtọ, aṣiwère, nigbati o ba pa ẹnu rẹ̀ mọ́, a kà a si ọlọgbọ́n; ẹniti o ba pa ẹnu rẹ̀ mọ́ si li amoye.
Ṣàwárí Owe 17:28
6
Owe 17:1
OKELE gbigbẹ, ti on ti alafia, o san jù ile ti o kún fun ẹran-pipa ti on ti ìja.
Ṣàwárí Owe 17:1
7
Owe 17:14
Ẹniti o daju fun omi dabi olupilẹṣẹ ìja; nitorina fi ìja silẹ ki o to di nla.
Ṣàwárí Owe 17:14
8
Owe 17:15
Ẹniti o da enia buburu lare, ati ẹniti o da olododo lẹbi, ani awọn mejeji irira ni loju Oluwa.
Ṣàwárí Owe 17:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò