1
Owe 23:24
Bibeli Mimọ
Baba olododo ni yio yọ̀ gidigidi: ẹniti o si bi ọmọ ọlọgbọ́n, yio ni ayọ̀ ninu rẹ̀.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 23:24
2
Owe 23:4
Máṣe lãla ati lọrọ̀: ṣiwọ kuro ninu imoye ara rẹ.
Ṣàwárí Owe 23:4
3
Owe 23:18
Nitoripe ikẹhin mbẹ nitõtọ; ireti rẹ kì yio si ke kuro.
Ṣàwárí Owe 23:18
4
Owe 23:17
Máṣe jẹ ki aiya rẹ ki o ṣe ilara si awọn ẹ̀lẹṣẹ, ṣugbọn ki iwọ ki o wà ni ibẹ̀ru Oluwa, li ọjọ gbogbo.
Ṣàwárí Owe 23:17
5
Owe 23:13
Máṣe fà ọwọ ibawi sẹhin kuro lara ọmọde, nitoripe bi iwọ ba fi paṣan nà a, on kì yio kú.
Ṣàwárí Owe 23:13
6
Owe 23:12
Fi aiya si ẹkọ́, ati eti rẹ si ọ̀rọ ìmọ.
Ṣàwárí Owe 23:12
7
Owe 23:5
Iwọ o ha fi oju rẹ wò o? kì yio si si mọ, nitoriti ọrọ̀ hu iyẹ-apá fun ara rẹ̀ bi ìdi ti nfò li oju ọrun.
Ṣàwárí Owe 23:5
8
Owe 23:22
Fetisi ti baba rẹ ti o bi ọ, má si ṣe gàn iya rẹ, nigbati o ba gbó.
Ṣàwárí Owe 23:22
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò