1
Owe 5:21
Bibeli Mimọ
Nitoripe ọ̀na enia mbẹ niwaju Oluwa, o si nṣiwọ̀n irin wọn gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 5:21
2
Owe 5:15
Mu omi lati inu kudu rẹ, ati omi ti nṣàn lati inu kanga rẹ.
Ṣàwárí Owe 5:15
3
Owe 5:22
Ẹ̀ṣẹ ẹni-buburu ni yio mu ontikararẹ̀, okùn ẹ̀ṣẹ ara rẹ̀ yio si dì i mu.
Ṣàwárí Owe 5:22
4
Owe 5:3-4
Nitori ti ète awọn ajeji obinrin a ma kán bi oyin, ẹnu rẹ̀ si kunna ju ororo lọ: Ṣugbọn igbẹhin rẹ̀ koro bi idápa, o si mú bi idà olojumeji.
Ṣàwárí Owe 5:3-4
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò