1
Owe 4:23
Bibeli Mimọ
Jù gbogbo ohun ipamọ́, pa aiya rẹ mọ́; nitoripe lati inu rẹ̀ wá ni orisun ìye.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 4:23
2
Owe 4:26
Ronu ipa-ọ̀na rẹ, gbogbo ọ̀na rẹ ni yio si fi idi mulẹ.
Ṣàwárí Owe 4:26
3
Owe 4:24
Mu arekereke kuro lọdọ rẹ, ati ète ẹ̀tan jina rére kuro lọdọ rẹ.
Ṣàwárí Owe 4:24
4
Owe 4:7
Ipilẹṣẹ ọgbọ́n ni lati ni ọgbọ́n: ati pẹlu ini rẹ gbogbo, ni oye.
Ṣàwárí Owe 4:7
5
Owe 4:18-19
Ṣugbọn ipa-ọ̀na awọn olõtọ dabi titàn imọlẹ, ti o ntàn siwaju ati siwaju titi di ọsangangan. Ọna awọn enia buburu dabi òkunkun: nwọn kò mọ̀ ohun ti nwọn ndugbolu.
Ṣàwárí Owe 4:18-19
6
Owe 4:6
Máṣe kọ̀ ọ silẹ, yio si mu ọ tọ́: fẹ ẹ, yio si pa ọ mọ́.
Ṣàwárí Owe 4:6
7
Owe 4:13
Di ẹkọ́ mu ṣinṣin, máṣe jẹ ki o lọ; pa a mọ́, nitori on li ẹmi rẹ.
Ṣàwárí Owe 4:13
8
Owe 4:14
Máṣe bọ si ipa-ọ̀na enia buburu, má si ṣe rìn li ọ̀na awọn enia ibi.
Ṣàwárí Owe 4:14
9
Owe 4:1
ENYIN ọmọ, ẹ gbọ́ ẹkọ́ baba, ki ẹ si fiyesi ati mọ̀ oye.
Ṣàwárí Owe 4:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò