1
Owe 8:35
Bibeli Mimọ
Nitoripe ẹniti o ri mi, o ri ìye, yio si ri ojurere Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí Owe 8:35
2
Owe 8:13
Ibẹ̀ru Oluwa ni ikorira ibi: irera, ati igberaga, ati ọ̀na ibi, ati ẹnu arekereke, ni mo korira.
Ṣàwárí Owe 8:13
3
Owe 8:10-11
Gbà ẹkọ mi, kì si iṣe fadaka; si gbà ìmọ jù wura àṣayan lọ. Nitori ti ìmọ jù iyùn lọ; ohun gbogbo ti a le fẹ, kò si eyi ti a le fi we e.
Ṣàwárí Owe 8:10-11
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò