1
O. Daf 100:5
Bibeli Mimọ
Nitori ti Oluwa pọ̀ li ore; ãnu rẹ̀ kò nipẹkun; ati otitọ rẹ̀ lati iran-diran.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 100:5
2
O. Daf 100:4
Ẹ lọ si ẹnu ọ̀na rẹ̀ ti ẹnyin ti ọpẹ, ati si agbala rẹ̀ ti ẹnyin ti iyìn: ẹ ma dupẹ fun u, ki ẹ si ma fi ibukún fun orukọ rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 100:4
3
O. Daf 100:2
Ẹ fi ayọ̀ sìn Oluwa: ẹ wá ti ẹnyin ti orin si iwaju rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 100:2
4
O. Daf 100:3
Ki ẹnyin ki o mọ̀ pe Oluwa, on li Ọlọrun: on li o dá wa, tirẹ̀ li awa; awa li enia rẹ̀, ati agutan papa rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 100:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò