1
O. Daf 101:3
Bibeli Mimọ
Emi ki yio gbé ohun buburu siwaju mi: emi korira iṣẹ awọn ti o yapa, kì yio fi ara mọ mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 101:3
2
O. Daf 101:2
Emi o ma rìn ìrin mi pẹlu ọgbọ́n li ọ̀na pipé. Nigbawo ni iwọ o tọ̀ mi wá! emi o ma rìn ninu ile mi pẹlu aiya pipé.
Ṣàwárí O. Daf 101:2
3
O. Daf 101:6
Oju mi yio wà lara awọn olõtọ, ki nwọn ki o le ma ba mi gbe: ẹniti o ba nrìn li ọ̀na pipé, on ni o ma sìn mi.
Ṣàwárí O. Daf 101:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò