1
O. Daf 104:34
Bibeli Mimọ
Jẹ ki iṣaro mi ki o mu inu rẹ̀ dùn: emi o mã yọ̀ ninu Oluwa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 104:34
2
O. Daf 104:33
Emi o ma kọrin si Oluwa nigbati mo wà lãye: emi o ma kọrin iyìn si Ọlọrun mi ni igba aiye mi.
Ṣàwárí O. Daf 104:33
3
O. Daf 104:1
FI ibukún fun Oluwa, iwọ ọkàn mi. Oluwa, Ọlọrun mi, iwọ tobi jọjọ: ọlá ati ọla-nla ni iwọ wọ̀ li aṣọ.
Ṣàwárí O. Daf 104:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò