1
O. Daf 105:1
Bibeli Mimọ
Ẹ fi ọpẹ fun Oluwa? ẹ pè orukọ rẹ̀: ẹ fi iṣẹ rẹ̀ hàn ninu awọn enia.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 105:1
2
O. Daf 105:4
Ẹ ma wá Oluwa ati ipá rẹ̀: ẹ ma wá oju rẹ̀ nigbagbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 105:4
3
O. Daf 105:3
Ẹ ma ṣogo li orukọ rẹ̀ mimọ́; jẹ ki aiya awọn ti nwá Oluwa ki o yọ̀.
Ṣàwárí O. Daf 105:3
4
O. Daf 105:2
Ẹ kọrin si i, ẹ kọ orin mimọ́ si i: ẹ ma sọ̀rọ iṣẹ iyanu rẹ̀ gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 105:2
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò