1
O. Daf 108:13
Bibeli Mimọ
Nipasẹ Ọlọrun li awa o ṣe akin; nitori on ni yio tẹ̀ awọn ọta wa mọlẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 108:13
2
O. Daf 108:4
Nitori ti ãnu rẹ tobi jù ọrun lọ: ati otitọ rẹ titi de awọsanma.
Ṣàwárí O. Daf 108:4
3
O. Daf 108:1
OLỌRUN, ọkàn mi ti mura, emi o ma kọrin, emi o si ma fi ogo mi kọrin iyìn.
Ṣàwárí O. Daf 108:1
4
O. Daf 108:12
Fun wa ni iranlọwọ ninu ipọnju: nitori asan ni iranlọwọ enia.
Ṣàwárí O. Daf 108:12
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò