1
O. Daf 109:30
Bibeli Mimọ
Emi o ma fi ẹnu mi yìn Oluwa gidigidi; nitõtọ, emi o ma yìn i lãrin ọ̀pọ enia.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 109:30
2
O. Daf 109:26
Ràn mi lọwọ, Oluwa Ọlọrun mi: gbà mi gẹgẹ bi ãnu rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 109:26
3
O. Daf 109:31
Nitori ti yio duro li ọwọ ọtún olupọnju, lati gbà a lọwọ awọn ti o nda ọkàn rẹ̀ lẹbi.
Ṣàwárí O. Daf 109:31
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò