1
O. Daf 115:1
Bibeli Mimọ
KÌ iṣe fun wa, Oluwa, kì iṣe fun wa, bikoṣe orukọ rẹ li a fi ogo fun nitori ãnu rẹ, ati nitori otitọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 115:1
2
O. Daf 115:14
Oluwa yio mu nyin bisi i siwaju ati siwaju, ẹnyin ati awọn ọmọ nyin.
Ṣàwárí O. Daf 115:14
3
O. Daf 115:11
Ẹnyin ti o bẹ̀ru Oluwa, gbẹkẹle Oluwa: on ni iranlọwọ wọn ati asà wọn.
Ṣàwárí O. Daf 115:11
4
O. Daf 115:15
Ẹnyin li ẹni-ibukún Oluwa, ti o da ọrun on aiye.
Ṣàwárí O. Daf 115:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò