1
O. Daf 119:105
Bibeli Mimọ
Ọ̀rọ rẹ ni fitila fun ẹsẹ̀ mi, ati imọlẹ si ipa ọ̀na mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 119:105
2
O. Daf 119:11
Ọ̀rọ rẹ ni mo pamọ́ li aiya mi, ki emi ki o má ba ṣẹ̀ si ọ.
Ṣàwárí O. Daf 119:11
3
O. Daf 119:9
Nipa ewo li ọdọmọkunrin yio fi mu ọ̀na rẹ̀ mọ́? nipa ikiyesi gẹgẹ bi ọ̀rọ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 119:9
4
O. Daf 119:2
Ibukún ni fun awọn ti npa ẹri rẹ̀ mọ́, ti si nwá a kiri tinu-tinu gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 119:2
5
O. Daf 119:114
Iwọ ni ibi ipamọ́ mi ati asà mi: emi nṣe ireti ninu ọ̀rọ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 119:114
6
O. Daf 119:34
Fun mi li oye, emi o si pa ofin rẹ mọ́; nitõtọ, emi o ma kiyesi i tinutinu mi gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 119:34
7
O. Daf 119:36
Fa aiya mi si ẹri rẹ, ki o má si ṣe si oju-kòkoro.
Ṣàwárí O. Daf 119:36
8
O. Daf 119:71
O dara fun mi ti a pọ́n mi loju; ki emi ki o le kọ́ ilana rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 119:71
9
O. Daf 119:50
Eyi ni itunu mi ninu ipọnju mi: nitori ọ̀rọ rẹ li o sọ mi di ãye.
Ṣàwárí O. Daf 119:50
10
O. Daf 119:35
Mu mi rìn ni ipa aṣẹ rẹ; nitori ninu rẹ̀ ni didùn inu mi.
Ṣàwárí O. Daf 119:35
11
O. Daf 119:33
Oluwa, kọ́ mi li ọ̀na rẹ; emi o si ma pa a mọ́ de opin.
Ṣàwárí O. Daf 119:33
12
O. Daf 119:28
Ọkàn mi nrọ fun ãrẹ̀: iwọ mu mi lara le gẹgẹ bi ọ̀rọ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 119:28
13
O. Daf 119:97
Emi ti fẹ ofin rẹ to! iṣaro mi ni li ọjọ gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 119:97
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò