1
O. Daf 121:1-2
Bibeli Mimọ
EMI o gbé oju mi si ori oke wọnnì, nibo ni iranlọwọ mi yio ti nwa? Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 121:1-2
2
O. Daf 121:7-8
Oluwa yio pa ọ mọ́ kuro ninu ibi gbogbo: yio pa ọkàn rẹ mọ́. Oluwa yio pa alọ ati àbọ rẹ mọ́ lati igba yi lọ, ati titi lailai.
Ṣàwárí O. Daf 121:7-8
3
O. Daf 121:3
On kì yio jẹ́ ki ẹsẹ rẹ ki o yẹ̀; ẹniti npa ọ mọ́ kì yio tõgbe.
Ṣàwárí O. Daf 121:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò