O. Daf 121:1-2

O. Daf 121:1-2 YBCV

EMI o gbé oju mi si ori oke wọnnì, nibo ni iranlọwọ mi yio ti nwa? Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye.