1
O. Daf 135:6
Bibeli Mimọ
Ohunkohun ti o wù Oluwa, on ni iṣe li ọrun, ati li aiye, li okun, ati ni ọgbun gbogbo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 135:6
2
O. Daf 135:3
Ẹ yìn Oluwa: nitori ti Oluwa ṣeun; ẹ kọrin iyìn si orukọ rẹ̀; ni orin ti o dùn.
Ṣàwárí O. Daf 135:3
3
O. Daf 135:13
Oluwa, orukọ rẹ duro lailai; iranti rẹ Oluwa, lati iran-diran.
Ṣàwárí O. Daf 135:13
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò