1
O. Daf 14:1
Bibeli Mimọ
AṢIWERE wi li ọkàn rẹ̀ pe, Ọlọrun kò si. Nwọn bajẹ, nwọn si nṣe iṣẹ irira, kò si ẹniti nṣe rere.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 14:1
2
O. Daf 14:2
Oluwa bojuwò lati ọrun wá sara awọn ọmọ enia, lati wò bi ẹnikan wà ti oye ye, ti o si nwá Ọlọrun.
Ṣàwárí O. Daf 14:2
3
O. Daf 14:3
Gbogbo wọn li o si jumọ yà si apakan, nwọn si di elẽri patapata; kò si ẹniti nṣe rere, kò si ẹnikan.
Ṣàwárí O. Daf 14:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò