1
O. Daf 19:14
Bibeli Mimọ
Jẹ ki ọ̀rọ ẹnu mi, ati iṣaro ọkàn mi, ki o ṣe itẹwọgba li oju rẹ, Oluwa, agbara mi, ati oludande mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 19:14
2
O. Daf 19:7
Ofin Oluwa pé, o nyi ọkàn pada: ẹri Oluwa daniloju, o nsọ òpè di ọlọgbọ́n.
Ṣàwárí O. Daf 19:7
3
O. Daf 19:1
AWỌN ọrun nsọ̀rọ ogo Ọlọrun; ati ofurufu nfi iṣẹ ọwọ rẹ̀ han.
Ṣàwárí O. Daf 19:1
4
O. Daf 19:8
Ilana Oluwa tọ́, o nmu ọkàn yọ̀: aṣẹ Oluwa ni mimọ́, o nṣe imọlẹ oju.
Ṣàwárí O. Daf 19:8
5
O. Daf 19:9
Ẹ̀ru Oluwa mọ́, pipẹ ni titi lai; idajọ Oluwa li otitọ, ododo ni gbogbo wọn.
Ṣàwárí O. Daf 19:9
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò