1
O. Daf 20:7
Bibeli Mimọ
Awọn ẹlomiran gbẹkẹle kẹkẹ́, awọn ẹlomiran le ẹṣin; ṣugbọn awa o ranti orukọ Oluwa Ọlọrun wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 20:7
2
O. Daf 20:4
Ki o fi fun ọ gẹgẹ bi ti inu rẹ, ki o si mu gbogbo ìmọ rẹ ṣẹ.
Ṣàwárí O. Daf 20:4
3
O. Daf 20:1
KI Oluwa ki o gbohùn rẹ li ọjọ ipọnju; orukọ Ọlọrun Jakobu ki o dàbobo ọ.
Ṣàwárí O. Daf 20:1
4
O. Daf 20:5
Awa o ma kọrin ayọ̀ igbala rẹ, ati li orukọ Ọlọrun wa li awa o fi ọpágun wa de ilẹ; ki Oluwa ki o mu gbogbo ibère rẹ ṣẹ.
Ṣàwárí O. Daf 20:5
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò