1
O. Daf 30:5
Bibeli Mimọ
Nitoripe, ni iṣẹju kan ni ibinu rẹ̀ ipẹ́, li ojurere rẹ̀ ni ìye gbe wà; bi ẹkun pẹ di alẹ kan, ṣugbọn ayọ̀ mbọ li owurọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 30:5
2
O. Daf 30:11-12
Iwọ ti sọ ikãnu mi di ijó fun mi; iwọ ti bọ aṣọ-ọ̀fọ mi kuro, iwọ si fi ayọ̀ dì mi li àmure. Nitori idi eyi ni ki ogo mi ki o le ma kọrin si ọ, ki o má si ṣe dakẹ. Oluwa Ọlọrun mi, emi o ma fi iyìn fun ọ lailai.
Ṣàwárí O. Daf 30:11-12
3
O. Daf 30:2
Oluwa Ọlọrun mi, emi kigbe pè ọ, iwọ si ti mu mi lara da.
Ṣàwárí O. Daf 30:2
4
O. Daf 30:4
Kọrin si Oluwa, ẹnyin enia rẹ̀ mimọ́, ki ẹ si ma dupẹ ni iranti ìwa-mimọ́ rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 30:4
5
O. Daf 30:1
EMI o kokiki rẹ, Oluwa; nitori iwọ li o gbé mi leke, ti iwọ kò si jẹ ki awọn ọta mi ki ó yọ̀ mi.
Ṣàwárí O. Daf 30:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò