1
O. Daf 32:8
Bibeli Mimọ
Emi o fi ẹsẹ̀ rẹ le ọ̀na, emi o si kọ́ ọ li ọ̀na ti iwọ o rìn: emi o ma fi oju mi tọ́ ọ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 32:8
2
O. Daf 32:7
Iwọ ni ibi ipamọ́ mi: iwọ o pa mi mọ́ kuro ninu iṣẹ́; iwọ o fi orin igbala yi mi ka kiri.
Ṣàwárí O. Daf 32:7
3
O. Daf 32:5
Emi jẹwọ ẹ̀ṣẹ mi fun ọ, ati ẹ̀ṣẹ mi li emi kò si fi pamọ́. Emi wipe, emi o jẹwọ ìrekọja mi fun Oluwa: iwọ si dari ẹbi ẹ̀ṣẹ mi jì.
Ṣàwárí O. Daf 32:5
4
O. Daf 32:1
IBUKÚN ni fun awọn ti a dari irekọja wọn jì, ti a bò ẹ̀ṣẹ wọn mọlẹ.
Ṣàwárí O. Daf 32:1
5
O. Daf 32:2
Ibukún ni fun ọkunrin na ẹniti Oluwa kò kà ẹ̀ṣẹ si lọrun, ati ninu ẹmi ẹniti ẹ̀tan kò si.
Ṣàwárí O. Daf 32:2
6
O. Daf 32:6
Nitori eyi li olukulùku ẹni ìwa-bi-ọlọrun yio ma gbadura si ọ ni igba ti a le ri ọ: nitõtọ ninu iṣan-omi nla, nwọn kì yio sunmọ ọdọ rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 32:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò