1
O. Daf 4:8
Bibeli Mimọ
Emi o dubulẹ pẹlu li alafia, emi o si sùn; nitori iwọ, Oluwa, nikanṣoṣo li o nmu mi joko li ailewu.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 4:8
2
O. Daf 4:4
Ẹ duro ninu ẹ̀ru, ẹ má si ṣe ṣẹ̀; ẹ ba ọkàn nyin sọ̀rọ lori ẹní nyin, ki ẹ si duro jẹ.
Ṣàwárí O. Daf 4:4
3
O. Daf 4:1
GBOHÙN mi nigbati mo ba npè, Ọlọrun ododo mi: iwọ li o da mi ni ìde ninu ipọnju; ṣe ojurere fun mi, ki o si gbọ́ adura mi.
Ṣàwárí O. Daf 4:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò