1
O. Daf 62:8
Bibeli Mimọ
Gbẹkẹle e nigbagbogbo; ẹnyin enia, tú ọkàn nyin jade niwaju rẹ̀; Ọlọrun àbo fun wa.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 62:8
2
O. Daf 62:5
Ọkàn mi, iwọ sa duro jẹ de Ọlọrun; nitori lati ọdọ rẹ̀ wá ni ireti mi.
Ṣàwárí O. Daf 62:5
3
O. Daf 62:6
On nikan li apata mi ati igbala mi: on li àbo mi; a kì yio ṣi mi ni ipò.
Ṣàwárí O. Daf 62:6
4
O. Daf 62:1
ỌLỌRUN nikan li ọkàn mi duro jẹ dè; lati ọdọ rẹ̀ wá ni igbala mi.
Ṣàwárí O. Daf 62:1
5
O. Daf 62:2
On nikan li apata mi ati igbala mi; on li àbo mi, emi kì yio ṣipò pada jọjọ.
Ṣàwárí O. Daf 62:2
6
O. Daf 62:7
Nipa Ọlọrun ni igbala mi, ati ogo mi: apata agbara mi, àbo mi si mbẹ ninu Ọlọrun.
Ṣàwárí O. Daf 62:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò