1
O. Daf 63:1
Bibeli Mimọ
ỌLỌRUN, iwọ li Ọlọrun mi; ni kutukutu li emi o ma ṣafẹri rẹ; ongbẹ rẹ ngbẹ ọkàn mi, ẹran-ara mi fà si ọ ni ilẹ gbigbẹ, ati ilẹ ti npongbẹ, nibiti omi kò gbe si.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 63:1
2
O. Daf 63:3
Nitori ti iṣeun-ifẹ rẹ san jù ìye lọ, ète mi yio ma yìn ọ.
Ṣàwárí O. Daf 63:3
3
O. Daf 63:4
Bayi li emi o ma fi ibukún fun ọ niwọnbi mo ti wà lãye: emi o ma gbé ọwọ mi soke li orukọ rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 63:4
4
O. Daf 63:2
Bayi li emi ti wò ọ ninu ibi-mimọ́, lati ri agbara rẹ ati ogo rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 63:2
5
O. Daf 63:7-8
Nitoripe iwọ li o ti nṣe iranlọwọ mi, nitorina li ojiji iyẹ́-apa rẹ li emi o ma yọ̀. Ọkàn mi ntọ̀ ọ lẹhin girigiri: ọwọ ọtún rẹ li o gbé mi ró.
Ṣàwárí O. Daf 63:7-8
6
O. Daf 63:6
Nigbati mo ba ranti rẹ lori ẹní mi, ti emi si nṣe aṣaro rẹ ni iṣọ oru.
Ṣàwárí O. Daf 63:6
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò