Bayi li emi o ma fi ibukún fun ọ niwọnbi mo ti wà lãye: emi o ma gbé ọwọ mi soke li orukọ rẹ.
N óo máa yìn ọ́ títí ayé mi; n óo máa tẹ́wọ́ adura sí ọ.
Èmi ó yìn ọ́ níwọ̀n ìgbà tí mo wà láààyè, èmi ó gbé ọwọ́ sókè, èmi ó sì pe orúkọ rẹ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò