1
O. Daf 64:10
Bibeli Mimọ
Olododo yio ma yọ̀ nipa ti Oluwa, yio si ma gbẹkẹle e; ati gbogbo ẹni-iduro-ṣinṣin li aiya ni yio ma ṣogo.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 64:10
2
O. Daf 64:1
ỌLỌRUN, gbohùn mi ninu aroye mi: pa ẹmi mi mọ́ lọwọ ẹ̀ru ọta nì.
Ṣàwárí O. Daf 64:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò