1
O. Daf 65:4
Bibeli Mimọ
Alabukún-fun li ẹniti iwọ yàn, ti iwọ si mu lati ma sunmọ ọdọ rẹ, ki o le ma gbe inu agbala rẹ wọnni: ore inu ile rẹ yio tẹ́ wa lọrùn, ani ti tempili mimọ́ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 65:4
2
O. Daf 65:11
Iwọ fi ore rẹ de ọdun li ade; ọrá nkán ni ipa-ọ̀na rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 65:11
3
O. Daf 65:5
Ohun iyanu nipa ododo ni iwọ fi da wa lohùn, Ọlọrun igbala wa: ẹniti iṣe igbẹkẹle gbogbo opin aiye, ati awọn ti o jina réré si okun.
Ṣàwárí O. Daf 65:5
4
O. Daf 65:3
Ọ̀ran aiṣedede bori mi: bi o ṣe ti irekọja wa ni, iwọ ni yio wẹ̀ wọn nù kuro.
Ṣàwárí O. Daf 65:3
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò