1
O. Daf 70:4
Bibeli Mimọ
Ki gbogbo awọn ti nwá ọ ki o ma yọ̀, ki inu wọn ki o si ma dùn nipa tirẹ: ki iru awọn ti o si fẹ igbala rẹ ki o ma wi nigbagbogbo pe, Ki a gbé Ọlọrun ga!
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 70:4
2
O. Daf 70:5
Ṣugbọn talaka ati alaini li emi: Ọlọrun, yara si mi: iwọ li oluranlọwọ ati olugbala mi: Oluwa, máṣe pẹ́ titi.
Ṣàwárí O. Daf 70:5
3
O. Daf 70:1
ỌLỌRUN, yara gbà mi; Oluwa, yara lati ràn mi lọwọ.
Ṣàwárí O. Daf 70:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò