1
O. Daf 71:5
Bibeli Mimọ
Nitori iwọ ni ireti mi, Oluwa Ọlọrun; iwọ ni igbẹkẹle mi lati igba ewe mi.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 71:5
2
O. Daf 71:3
Iwọ ni ki o ṣe ibujoko apata mi, nibiti emi o gbe ma rè nigbagbogbo: iwọ ti paṣẹ lati gbà mi; nitori iwọ li apata ati odi agbara mi.
Ṣàwárí O. Daf 71:3
3
O. Daf 71:14
Ṣugbọn emi o ma reti nigbagbogbo, emi o si ma fi iyìn kún iyìn rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 71:14
4
O. Daf 71:1
OLUWA, iwọ ni mo gbẹkẹ mi le: lai máṣe jẹ ki a dãmu mi.
Ṣàwárí O. Daf 71:1
5
O. Daf 71:8
Jẹ ki ẹnu mi ki o kún fun iyìn rẹ ati fun ọlá rẹ li ọjọ gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 71:8
6
O. Daf 71:15
Ẹnu mi yio ma fi ododo rẹ ati igbala rẹ hàn li ọjọ gbogbo; emi kò sa mọ̀ iye rẹ̀.
Ṣàwárí O. Daf 71:15
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò