1
O. Daf 73:26
Bibeli Mimọ
Ẹran-ara mi ati aiya mi di ãrẹ̀ tan: ṣugbọn Ọlọrun ni apata aiya mi, ati ipin mi lailai.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 73:26
2
O. Daf 73:28
Ṣugbọn o dara fun mi lati sunmọ Ọlọrun: emi ti gbẹkẹ mi le Oluwa Ọlọrun, ki emi ki o le ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ gbogbo.
Ṣàwárí O. Daf 73:28
3
O. Daf 73:23-24
Ṣugbọn emi wà pẹlu rẹ nigbagbogbo: iwọ li o ti di ọwọ ọtún mi mu. Iwọ o fi ìmọ rẹ tọ́ mi li ọ̀na, ati nigbẹhin iwọ o gbà mi sinu ogo.
Ṣàwárí O. Daf 73:23-24
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò