1
O. Daf 74:16
Bibeli Mimọ
Tirẹ li ọsán, tirẹ li oru pẹlu: iwọ li o ti pèse imọlẹ ati õrun.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 74:16
2
O. Daf 74:12
Nitori Ọlọrun li Ọba mi li atijọ wá, ti nṣiṣẹ igbala lãrin aiye.
Ṣàwárí O. Daf 74:12
3
O. Daf 74:17
Iwọ li o ti pàla eti aiye: iwọ li o ṣe igba ẹ̀run ati igba otutu.
Ṣàwárí O. Daf 74:17
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò