1
O. Daf 75:7
Bibeli Mimọ
Ṣugbọn Ọlọrun li onidajọ: o sọ ọkan kalẹ, o gbé ẹlomiran leke.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 75:7
2
O. Daf 75:1
ỌLỌRUN, iwọ li awa fi ọpẹ fun, iwọ li awa fi ọpẹ fun nitori orukọ rẹ sunmọ itosi, iṣẹ iyanu rẹ fi hàn.
Ṣàwárí O. Daf 75:1
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò