1
O. Daf 86:11
Bibeli Mimọ
Oluwa, kọ́ mi li ọ̀na rẹ; emi o ma rìn ninu otitọ rẹ: mu aiya mi ṣọkan lati bẹ̀ru orukọ rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 86:11
2
O. Daf 86:5
Nitori iwọ, Oluwa, o ṣeun, o si mura ati dariji; o si pọ̀ li ãnu fun gbogbo awọn ti nkepè ọ.
Ṣàwárí O. Daf 86:5
3
O. Daf 86:15
Ṣugbọn iwọ, Oluwa, li Ọlọrun ti o kún fun iyọ́nu, ati olore-ọfẹ, olupamọra, o si pọ̀ li ãnu ati otitọ.
Ṣàwárí O. Daf 86:15
4
O. Daf 86:12
Emi o yìn ọ, Oluwa Ọlọrun mi, tinutinu mi gbogbo: emi o si ma fi ogo fun orukọ rẹ titi lai.
Ṣàwárí O. Daf 86:12
5
O. Daf 86:7
Li ọjọ ipọnju mi, emi o kepè ọ: nitori ti iwọ o da mi lohùn.
Ṣàwárí O. Daf 86:7
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò