1
O. Daf 89:15
Bibeli Mimọ
Ibukún ni fun awọn enia ti o mọ̀ ohùn ayọ̀ nì: Oluwa, nwọn o ma rìn ni imọlẹ oju rẹ.
Ṣe Àfiwé
Ṣàwárí O. Daf 89:15
2
O. Daf 89:14
Otitọ ati idajọ ni ibujoko itẹ́ rẹ: ãnu ati otitọ ni yio ma lọ siwaju rẹ.
Ṣàwárí O. Daf 89:14
3
O. Daf 89:1
EMI o ma kọrin ãnu Oluwa lailai: ẹnu mi li emi o ma fi fi otitọ rẹ hàn lati irandiran.
Ṣàwárí O. Daf 89:1
4
O. Daf 89:8
Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, tani Oluwa alagbara bi iwọ? tabi bi otitọ rẹ ti o yi ọ ká.
Ṣàwárí O. Daf 89:8
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò