Ibukún ni fun awọn enia ti o mọ̀ ohùn ayọ̀ nì: Oluwa, nwọn o ma rìn ni imọlẹ oju rẹ.
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ó mọ ìhó ayọ̀ nnì, àwọn tí ń rìn ninu ìmọ́lẹ̀ ojurere rẹ, OLUWA
Ìbùkún ni fún àwọn ènìyàn tí wọn mọ ohùn ayọ̀ nì, OLúWA wọ́n ó máa rìn ní ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò